Ezekiel 22:28
28
Àti àwọn wòlíì rẹ́ ti ṣẹ̀tàn sí wọn, wọn ń rì ìran asán, wọn sì ń fọ àfọ̀ṣẹ èké sí wọn, wí pé, ‘Báyìí ní
Olúwa
Olódùmarè wí,’ nígbà tí ó ṣépè
Olúwa
kò sọ̀rọ̀.
Copyright information for
YorBMYO